Home Gospel Music Music: Olawunmi Olomola – Eleti Gbaroye

Music: Olawunmi Olomola – Eleti Gbaroye

Nigerian Gospel singer, Olawunmi Olomola  drops a new single titled “Eleti Gbaroye”

Stream and download below:

 

[media-downloader media_id=”697″ texts=”Download Here”]

Connect with Olawunmi Olomola on;
FB: @olawunmi olomola
Instagram: @olawunmi olomola, Twitter: @wumzyolomola

Lyrics:
[Chorus 1]
Eleti gbaroye
Eleti gbaroye
Gbo adura mi (2x)

[Verse 1]
Iwo nimo gbojule, Iwo nimo fehinti
Atofarati bi oke, Iwo nimo Simi le
Iwo nimo gbojule, Iwo nimo fehinti
Atofarati bi oke, Iwo nimo Simi le
Gbo adura mi, Gbo adura mi

[Verse 2]
Kabieysi, atobiju, Iwo l’oba awon oba
Iro olorun mi l’oke gbo, to dobale, toni Iwo leni to gaju lo
Ohun oba go n’iji gbo, to shi fila toni Iwo leni toga ju lo
Be tise l’ojo ojosi, be tise ni’gba woni
E tun lese juyen lo, etun lese ju gbogbo ohun timo lero lo

[Chorus 2]
Iwo nimo gbojule, Iwo nimo fehinti
Atofarati bi oke, Iwo nimo Simi le
Gbo adura mi

[ORIKI]

[Repeat Chorus 1 & 2]
Eleti gbaroye
Eleti gbaroye
Gbo adura mi (2x)

Iwo nimo gbojule, Iwo nimo fehinti
Atofarati bi oke, Iwo nimo Simi le
Gbo adura mi
Gbo adura mi
Gbo adura mi……………

Leave a Reply